A number of novel scientific and biotechnological exploits and interventions have been recorded in recent times. Of principal concern is the attempt by certain scientific researchers and practitioners to modify the genetic make-up of the human being at the embryonic stage in order to produce a more advanced form of human life. This attempt is motivated by the desire to enhance the quality of human life to such a degree that it renders us less vulnerable to debilitating diseases in general and other congenital medical disorders in particular.
This project, designated the Transgenic Human Embryo (THE) project, not only raises serious ethical questions regarding the justification for the defence of such a radical intervention in the “natural” process of human development: at a more fundamental ontological level, it challenges our very (self-) understanding of what it means to be a human being.
From a philosophical perspective, the THE project problematically privileges a Western-Eurocentric epistemological culturalist framework that is driven by “modern” ideas of scientific-technical rationality and progress, whose specific nature and normativity can be traced back to the European philosophical tradition of Enlightenment. From this perspective, the European Enlightenment conceptualization of the human being is (problematically) universalised as the only true and, therefore, “highest” form of human life, to the disregard of “other” (different) non-Western understandings of human life, especially the African philosophical understanding of humanness, which is presented in this study as a counter-discourse and critique of the universalising (hegemonic) Eurocentric assumptions and norms at the core of the THE project.
Ò̥pò̥ló᷂᷂᷂᷂pò̥ ni àwọn ojúlówó işè̥ takuntakun tí ìmò̥ ìjìnlè̥ sáyé̥nsì àti ìmò̥ è̥rọ tí ó sopò̥ mó̥ è̥mí ti şe àwárí ní àìpé̥ yìí. Èyí tí ó kan ni gbàngbàn ni ìgbìyànjú àwọn ò̥mò̥wé àti ò̥jò̥gbó̥n nínú ìmò̥ ìjìnlè̥ lati şe àyípadà èròjà abínibí ti è̥dá ènìyàn láti ipò ọlè̥-inú ní ò̥nà láti şe è̥dá ènìyàn tí ó gbé pé̥é̥lí ju ti àtè̥yìnwá lọ. Ìgbìyànjú yìí wáyé látàrí ìpòǹgbe fún ìyípadà ìwúlò ìgbésí ayé ọmọ è̥dá dé ìkòríìta tí a kì yóò jé̥ şubúşeré fún àwọn àrừn búburú, pàápàá jừlo, àwọn àrừn abínibí.
Işé̥ yìí, tí àfojúsứn rè̥ jé̥ işé̥ ti Ìyípadà Èròjà Abínibí làti inú oyún, pèsè idáláàre nipa ohun tó lé̥è̥tó̥ fún ìbéèrè tí ó je̥ mó̥ ìkìlé̥è̥yìn ètò ìdásí alágbára nínú ò̥nà ti “è̥dá” ti ènìyàn fi ndàgbà: bákàn náà ni ipele tí ó jinlè̥, ó tún şe ìpènijà fún òye (ti ara eni) nípa ohun tí jíjé̥ ènìyàn túmò̥ sí.
Lati ibi ojú ìmòye ti àròjinlè̥, işé̥ ti Ìyípadà Èròjà Abínibí làti inú oyún bu ọlá fún ò̥nà ìmò̥ tí ó wà ní ìbámu pè̥lú àşà àti àgbékalè̥ àwọn aláwò̥ funfun, èyí tí a darí nípa ọgbó̥n “ìgbàlódé” ti ìmò̥-ìjìnlè̥ sáyé̥nsì àti ti ìmò̥ è̥rọ tí ó mú làákàyè àti ìdàgbàsókè wá, èyí tí è̥dà àti àşe̥ rè̥ je̥yọ lati inú ọgbó̥n àròjinlè̥ àti ìşè̥şe ti àwọn aláwò̥ funfun tí ó nííşe pè̥lú ò̥làjú. Láti ibi ìmòye yíí, ìtúmò̥ tí ò̥làjú àwọn aláwò̥ funfun ní nípa ènìyàn jé̥ èyí tí ó fi (tìyọnutìyọnu) jé̥ gbajúgbajà gé̥g̥é̥ bi òótó̥ kan şooşo àti è̥dà tí ó “gajừ lọ” nípa ìgbésí ayé ènìyàn, ní ò̥nà tí ó fi ojú àbừkừn wo “àwọn” òye (mìíràn) tí kìi şe ti àwọn aláwò̥ funfun, pàápàá jừlọ èyí tí ó jé̥ ti ìmòye àti àròjinlè̥ ti àwọn aláwò̥ dúdú nípa jíjé̥ ènìyàn, èyí sì ni ìwáàdí ìjìnlè̥ yii wá gé̥gé̥ bí ìdojúkọ àti ìpèníjà sí èròngbà gbajúgbajà (ìjegába) ti àwọn aláwò̥ funfun àti àgbékalè̥ tí ó wà ni àárín gbừngbừn tí işé̥ ìwáàdí nípa Ìyípadà Èròjà Abínibí làti inú oyún.